SONG LYRICS:
“ Oná ti Olorun Ngbá {The ways of God}
——————————————-
« Les voies de Dieu sont mystérieuses » {The ways of God are mysterious }
« Ses voies, l'homme ne peut pas comprendre » {His ways man can not understand}
Come on now.. are you ready now?
Let’s go x3e Eii
Call…; Oná t’Olorun ngba sòrò o
Resp..; Oná t’Olorun ngba sòrò o
Call Oná t’Olorun ngba shi shé ré Layemi o sòrò oo
Resp..;Oná t’Olorun ngba sòrò o
Call ..; Oná re enikan Ko mò awamaridi ni
Resp..;Oná t’Olorun ngba sòrò o
Call..; Alaigbagbò won kiyo ri ogo Olorun
Resp..;Oná t’Olorun ngba sòrò o
Call..; I ask for bread you give me bakery eh Olorun Oshey
Resp..;Oná t’Olorun ngba sòrò o
Call..;I ask for water you open ocean for me o
Resp..;Oná t’Olorun ngba sòrò o
Call..; Oná re enikan komò yé o yé o yé
Resp..;Oná t’Olorun ngba sòrò o
To’ngbá ! To’ngbá …5xe
So rò! So rò
To’ngbá !To’ngbá
So rò! So rò
Vocal 1..
Idowu Santa mi arole ayefele,mo Gbé orinmi dę efarabàlé ké gbò mi,òná t’Olorun ngbá,ni ilė aye òna to sòrò ni Ko yé eni body rara.., Òba tá mu é ni tio ni àsò di eni to nii pupò,a mu Omo eru lasan jeun laàfin Òbá, Obá toun fi opė damu Ologbòn kabie osii ..
Call…; Oná t’Olorun ngba sòrò o
Resp..; Oná t’Olorun ngba sòrò o
Call..; Oná t’Olorun ngba shi shé ré Layemi o sòrò oo
Resp..;Oná t’Olorun ngba sòrò o
Call ..; Oná re enikan Ko mò awamaridi ni
Resp..;Oná t’Olorun ngba sòrò o
Call..; Alaigbagbò won kiyo ri ogo Olorun
Resp..;Oná t’Olorun ngba sòrò o
Call..; I ask for bread you give me bakery eh Olorun Oshey
Resp..;Oná t’Olorun ngba sòrò o
Call..;I ask for water you open ocean for me o
Resp..;Oná t’Olorun ngba sòrò o
Call..; Oná re enikan komò yé o yé o yé
Resp..;Oná t’Olorun ngba sòrò o
Vocal 2…
Awa ni iran ti nsé àferi ré Olorun Odo do, Olorun t’awa’nsin yi ni Olorun wa…Omo kiniu ama sę alaini ebi asima pawon, sugbon Awa to’nwa Oluwa akiyo sé alaini oun to dara..,ni Olorun wii baba wa
Oni ka tuju ka,owun ti ségun àyę kawa Oluwa ni gbá tá leri, kasunmo Olorun Oun bé ni tosii waa.. eh eh eh eh eh eh!!!
Call…; Oná t’Olorun ngba sòrò o
Resp..; Oná t’Olorun ngba sòrò o
Call Oná t’Olorun ngba shi shé ré Layemi o sòrò oo
Resp..;Oná t’Olorun ngba sòrò o
Call ..; Oná re enikan Ko mò awamaridi ni
Resp..;Oná t’Olorun ngba sòrò o
Call..; Alaigbagbò won kiyo ri ogo Olorun
Resp..;Oná t’Olorun ngba sòrò o
Call..; I ask for bread you give me bakery eh Olorun Oshey
Resp..;Oná t’Olorun ngba sòrò o
Call..;I ask for water you open ocean for me o
Resp..;Oná t’Olorun ngba sòrò o
Call..; Oná re enikan komò yé o yé o yé
Resp..;Oná t’Olorun ngba sòrò o
To’ngbá ! To’ngbá …5xe
So rò! So rò
To’ngbá !To’ngbá
So rò! So rò
To ‘ngbá sòrò.. To ‘ngbá sòrò
To ‘ngbá sòrò… Oná To ‘ngbá sòrò
Oná To’ngbá ! To’ngbá …5xe
So rò! So rò
To’ngbá !To’ngbá
So rò! So rò
Oná To ‘ngbá sòrò.. To ‘ngbá sòrò
Oná To ‘ngbá sòrò… Oná To ‘ngbá sòrò
Oná To ‘ngbá sòrò…!!!!
*lyrics written by Taiwoamen *
STREAM ON AUDIOMACK
0 Comments
Drop your comment: