"Ope Awa Laaye" is a song of gratitude to the Lord for keeping us safe from every dangers and pestilence of the world.
Every lyrical words of the song resonate with our day to day life activities... Inspired by the Holy Spirit to minister to every grateful heart out there. Despite all of the battles and challenges around us, the Bible says , "in everything we should give thanks to the Lord".. It sure will bless your life .
Lyrics:
Chrs: Ope, a waa laaye,
Atun wa laaye wa,
Oye ka ko Orin fun Oluwa,
To mu wa waa laaye .
1. Ero ota bii kaa shaati ku,
Bii kete won se lewa Lori,
Sugbon, Oga Ogo lo fajulo rehan,
Kii, se agbara wa(rara)
Awa o,
Awa oni Shai shope,
Fore tolu se fun wa,
Fun idaasii latooke wa,
Aanu nla la rigba (ope 2ce) ( Awalaye, Awa la laafia, aahh)
2. Opo enia lo sun to o jii mo,
Opo lowa ni ile iwosan,
Opo to San ju wa ti ko jalo,
Opo alaise lowa lewon ( ao fi yo won o)
Eni ba laaro jinle laye( Aaronu jinle la fiwa dupe)
Ako bi ati n fope foluwa,
Nitori,
Iji lotun ati idanwo losi,
Aanu nla la n rigba (ope 2ce)Chrs ( Ope oloore adaada tan, feni to lemi gbogbo enia , kakorin ayo soluwa, ooo)
3. Ba o tile ni a o toro je,
Oro re so wipe , ninu ohun gbogbo ka Sha maa dupe,
Nitori bemi ba shii wa, a ni ireti ninu Kristi wipe ojo ola wa yio daara,
Eni baa Moore oluwa, ko pelumi kajo dupe,
Nitori ko fiwa lawon ota lowo awa lalaafia, aanu nla lan rigba, chrus
( aanu n la laari , aanu lo gbe waduro, ki maa e se Nipa imo n se wa, tabi togbon orii)
4. Opa wa mo tile tile ,
Awon enia wa ni ibi gbogbo agbo ibi si won,
Ahh!!!!
Oore ofee nla yii showon ninu aye ti awaa,
Ofe lo fii fun wa,
Enia iba maa yin Oluwa, fun oore re Lori awa eda,
Nitori akaikatan loore olorun ninu aye wa,
Tori naa oye kakorin Ope si.
chrs ( ka jijo Ope, ka korin Ope , torolu se wa loore)
Egbega 3ce ebami gbe Jesu yii ga,
Egbega 3ce ebami yin baba logo,
Egbega, ebami gbega, egbe Jesu yii ga,
Oore to se fun mi opo egbega.
Chrs : Egbega 3ce ebami gbe Jesu yii ga,
Egbega 3ce ebami yin baba logo,
Egbega 3ce, ebami gbe Jesu yii ga,
Oore to se fun mi opo, egbega.
1. ooo ma fowo mi gbega, Mafi ijo mi gbega,
Mafohun mi gbega, ma fohun ti Mo ni yin baba logo,
Oore re Lori mi Opo kosee fenu so,
Akai niye loore daddy , egbeega.
chrs ( egbega 3ce) o, (eyin baba logo oooooo)
2. Lilo bibo mi, aanu nla ni morigba,
Iwa laye mi, olorun mi koseyin yin,
Gbogbo oun ti mo lako ja laye se beyin le pelu mi,
Iyin ni mo muwa falaabo eemi mi, egbeega.
Chrs : ( Edide ebami gbega, gbogbo enia egbe, ooooo)
3. Oku ni tori mi, kemi baa leye,
Ofara e rubo ese kale Rami pada,
Otun ji dide, lase so mi di edaa tuntun,
Jesu Olurapada mini , egbeegaa.
( Egbega 2ce, omode egbega, agba egbega,
oloore wa, alaanu, oloore ofee, egbega 3ce)
Artiste Biography. Praise Abiodun, a gospel singer known for songs such as Fogo Foluwa, Maje n Jiya, Ope Awa Laaye, Igbagbo mi, and Born on April 12, 1996 in Osun State, Ilesa. Currently based in Ogun state.
A graduate of the University of Ibadan-associated campus who is currently employed in the teaching profession. Passionate about gospel music and will pursue it with all zeal.
A composer and songwriter who seeks to know God more every day.
Hobbies include listening to music/singing, travelling, reading interesting stories, and seeing inspirational films.
She is single, cool, and collected, and her songs are inspired by the Holy Spirit. They also serve as a medium for proclaiming the gospel to the world at large. She is also influenced by other outstanding musicians and gospel ministers whose songs have blessed others in some way.
She attended the Grace Nursery and Primary School in Osun State. She also attended Ilesa Grammer School in Ilesa, Osun State.
Email: praise.abiodun2020@gmail.com
Facebook: Praise Abiodun.
Twitter: Praiseabiodun3.
Instagram username: praiseabiodun1.
TikTok: praiseabiodun28.
Ituneplay is a music promotional platform for artist and for people who love music.
The platform provides the latest songs and also allow people to promote their songs in ituneplay.
For more information on how to promote your song kindly call or WhatsApp 08062839840
2 Comments
Nice
Nice
Drop your comment: